1. Nigbati Oluwa mu ikolo sioni pada wa awa dabi eni to nla ala nigbayi Orin ayo si wa gba enu wa kan Okan wa Kun fayo latoke
Chorus:
Ayo orun wonu Okan wa ayo orun wonu Okan wa Ibanuje ko Raye mo laye wa ayo orun wonu Okan wa
2. Nigbayi lawon keferi wipe Oluwa tise ohun nla fun won Oluwa ti sohun nla fun wa nitorina awa yo awa yo Oluwa mu ikolo sioni pada wa bi isan Omi gusu awon ti fomije funrugbin yo fayo ka eni tin fin ekun rin tosi gbe Irugbin lo ni yo fi ayo pada wa sile.
Chorus:
Ayo orun wa wonu Okan wa ayo orun kunu aye wa Ibanuje ko Raye mo laye wa ayo orun wonu Okan wa.